Category Archives: Èdè Yorùbá

Èdè Yorùbá Ní báyìí, tí a bá wo èdè Yorùbá, àwọn onímọ̀ pín èdè náà sábẹ́ ẹ̀yà Kwa nínú ẹbí èdè Niger-Congo. Wọ́n tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ẹ̀yà Kwa yìí ló wọ́pọ̀ jùlọ ní sísọ, ní ìwọ̀ oòrùn aláwọ̀ dúdú fún ẹgbẹ̣ẹgbẹ̀rún ọdún. Àwọn onímọ̀ èdè kan tilẹ̀ ti fi ìdí ọ̀rọ̀ múlẹ̀ pé láti orírun kan náà ni àwọn èdè bí Yorùbá, Kru, Banle, Twi, Ga, Ewe, Fon, Edo, Nupe, Igbo, Idoma, Efik àti Ijaw ti bẹ̀rẹ̀ sí yapa gẹ́gẹ́ èdè ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tó dúró láti bí ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ọ̀dún sẹ́yìn.

òṣùpá – Èdè Yorùbá – Word of the Day (2017-12-03)

Òṣùpá

Òsùpá je oluyipo ile-aye. Arinidaji jijinnasi lati ile aye titi de ori osupa je 384,403 kilometres. Eyi je ilaarin ona 30 ile-aye. Ilaarin osupa je 3,474 kilometres – to je pe die lo fi ju okan ninu merin lo si ti ile-aye. Eyi si je pe kikuninu (volume) osupa je 1/50th pere ti ile-aye. Fifa iwuwosi re je 1/6th si ti ile-aye. Osupa n yipo ile-aye ni ekan larin ojo 27.3 (ojo metadinlogbon ole ni wakati meta).

Èdè Yorùbá – 2017-05-01

So, Yorùbà is a tonal language, ok. It is *not* monosyllabic, though. Not so OK :/

  • igba ‘two hundred’
  • igbá ‘calabash’
  • ìgbà ‘time’
  • ìgba ‘the season when perennial crops have the least production’
  • ìgbá ‘garden egg’
  • igbà ‘climbing rope’

 

  • ọkọ ‘husband’
  • ọkọ́ ‘hoe’
  • ọ̀kọ̀ ‘spear’
  • ọkọ̀ ‘vehicle’